BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Wo ohun tí àwọn aráàlú ń là kọjá nítorí àìrí epo bẹntiróòlù rà lónìí
Bo tilẹ jẹ pe ajọ NNPCL to n ri si ọrọ epo rọbi sọ lopin ọsẹ wi pe awọn ni epo to to ọmọ Naijiria lo ni ipamọ, alukoro ẹgbẹ IPMAN, Ọgbẹni Chinedu Ukadike ti fidi rẹ mulẹ pe ko si epo to to araalu lo ni Naijiria lọwọ yii.
Kí ló dé tí àwọn èèyàn kan ń fi apá jánú lórí ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀yọ́?
Ẹwẹ, ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) n'ipinlẹ Ọyọ ti fi ọrọ lede wi pe irọ lasan ni pe eto idibo naa lọ ni irọwọrọsẹ,
Ọ̀dọ́mọkùrin tó fẹ́ràn láti máa já ọ̀kadà gbà há l’Ékìtì
A gbọ pe asiko ti Bernard n gbiyanju lati digun gba ọkada lọwọ ọkunrin ọlọkada kan ni ọwọ palaba rẹ segi, ko to di pe wọn lọ fa a le awọn ọlọpaa ẹkun Ọyẹ lọwọ.
Ìbálòpọ̀ akọ sí akọ, abo sí abo di ìwà ọ̀daràn ni Iraq
Ẹwọn ọdun mẹwaa si mẹẹẹdogun ni wọn ni ẹni tọwọ ba tẹ yoo fi jura labẹ aba tuntun yii.
Wo àwọn nǹkan méje tí o kò mọ̀ nípa Egbin Orun, akọrin ẹ̀mí tó dolóògbé
Olorin ẹmi bii tiẹ, Esther Igbẹkẹle, lo fi iroyin iku naa soju opo Instagram rẹ lọjọ Satide, ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kẹrin yii.
Ọlọ́pàá sọ̀rọ̀ lórí ikú adarí ikọ̀ ìpolongo gómìnà Aiyedatiwa l’Ondo tí agbébọn pa
Alukoro ni oun ko tii le sọ boya iṣekupani ọhun lọwọ oṣelu ninu.
Ọ̀pọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ Fáṣítì US dèrò àhámọ́ nítorí ìfẹhonúhàn tí wọ́n ṣe lórí ìkọlù Israel sí Gaza
Oludije aarẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Green Party, Jill Stein naa pẹlu awọn eeyan to wa ni ahamọ Ileeṣẹ ọlọpaa.
Ọmọ mẹ́wàá ni Ọlọ́run fún mi ṣùgbọ́n méje ló jáde láyé nípasẹ̀ ààrùn Measles- Olùṣọ́-Aguntan Adio
Olusọ aguntan yii to jẹ afọju ba BBC News Yoruba sọrọ lori irinajo aiye rẹ bi o ṣe di pe o padanu oju rẹ.
Ìwọ́de gbòde ní Australia láti fòpin sí pípa àwọn obìnrin lọ́nà àìtọ́
Olóòtú ìjọba Australia, Anthony Albanese ní ọ̀rọ̀ náà ti di ohun tó ń dààmú gbogbo orílẹ̀ èdè àwọn.
Èèyàn kan ló kú níbi ìbúgbàmù afẹ́fẹ́ ìdáná l’Abẹokuta, mẹ́rin kọ́-FRSC
Tanka to gbe gaasi naa ni wọn lo padanu ijanu rẹ (brake failure), eyi lo si fa a to fi fori sọ pepele ti wọn fi dabuu ọna.
Wo ohun tó ṣẹlẹ̀ s’áwọn tó fẹ̀hónú hàn nítorì ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ ní Benin
Nibi ti iwọde ọhun ti n lọ lọwọ lawọn ọlọpaa ti ko mẹtadinlogun (17) ninu awọn oluwọde naa.
Ìròyìn Àkàgbádùn
Fídíò, Ṣé bí adẹrìn-ínpòṣónú Layi Wasabi ṣe mú lẹ́nu ló láyà tó?Duration, 3,50
Layi Wasabi darapọ̀ mọ́ BBC News Yorùbá lórí ètò 'Só o láyà' tọ̀tẹ̀ yìí lati mọ̀ bí Yorùbá rẹ̀ ṣe dáńtọ́ tó.
'Ìbejì ni wá ṣùgbọ́n àyẹ̀wò DNA ní bàbá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló bí wa'
Awọn onimọ sayensi ṣalaye pe, iru iṣẹlẹ yii ṣọwọn, ti ko si ju mẹwa lọ to ni akọsilẹ lagbaye ṣugbọn o wọpọ laarin ẹranko.
Aláboyún wà lára èèyàn tó ti pàdánù ẹ̀mí níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná ní Rivers
Lasiko ti a n kọ iroyin yii, ko ti i sẹni to mọ iye eeyan to ku tabi farapa ninu iṣẹlẹ naa.
Ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní wó àwọn ilé tó wà lójú ọ̀nà mọ́rosẹ̀ Eko sí Calabar tí iṣẹ́ ń lọ lórí rẹ̀
Alakooso naa rọ gbogbo awọn tijọba ti sami sile wọn lati wo lulẹ, pe ki wọn tete lọ si ileeṣẹ ijọba ipinlẹ Eko, lati pari eto gbogbo to yẹ.
Yahaya Bello pe Alága EFCC lẹ́jọ́, ó ló tàpá sí àṣẹ kóòtù lórí ọ̀rọ̀ oun
Ẹsun ti Yahaya Bello n ka si Alaga EFCC lẹsẹ ni pe ile-ẹjọ ti paṣẹ fun un tẹlẹ pe ki wọn ma ti i gbiyanju lati mu oun rara.
Bàbá mi Ogunjimi ti máa ń fi gbogbo ìgbà múra sílẹ̀ de ikú- Ismailia ọmọ olóògbé
Ismaila ni "baba mi Ganiyu Akinpelu jẹ eeyan takuntakun ninu ẹgbẹ osere tiata ati ninu ilu.''
Ilé alájà dàwó lu òṣìṣẹ́ márùndínlógún ní Kano
Ko tii si ẹni le sọ iye awọn eeyan ti wahala naa ṣe lọṣẹ.
Òní lónìí ń jẹ́ ní ìpínlẹ̀ Oyo bí ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ yóò ṣe gbérasọ
O kere tan, awọn ẹṣọ eleto aabo bii ẹgbẹrun mẹẹdogun ni ajọ naa ti gba lati mojuto eto idibo naa, bakan naa si ni ajọ OYSIEC ti fi iroyin lede nipa igbanisiṣẹ awọn oṣiṣẹ eleto idibo bii ẹgbẹrun lọna ogoji ti yoo ṣe atọkun eto idibo naa jakejado ipinlẹ Ọyọ.
Oyún oṣù méje ààbọ̀, tí Dókítà gbé jáde nínú ìyá rẹ̀ ní Gaza, ti jáde láyé
Ẹlẹmi gba ẹmi ọmọ jojolo naa ni Ọjọbọ ana, ti wọn si ti sin i si ẹgbẹ iya rẹ ẹni ti wọn fi orukọ rẹ sọ ọ.
Wo pàtàkì iṣan tó ń ṣiṣẹ́ bíi ọkàn, mú kí èèyàn fẹsẹ̀ méjì rìn, ó tún ń mú kí ẹ̀jẹ̀ ṣàn lára
Dokita Carles Pedret, akọṣẹmọṣẹ lati ileewe to n ri si ilera nipa ere idaraya ni Yunifasiti Barcelona ni iṣan Soleus nilo lati maa ṣiṣẹ deede keeyan le wa lalaafia ara.
Àgbàrá òjò gbé èèyàn 150 lọ, 51,000 míì di aláìnílélórí
Olugbe agbegbe Siha ni ariwa Tanzania sọ fun BBC pe ile oun ti dawo, oun si ti wa ni korofo bayii.
Àwọn gómìnà lápá Àríwá lọ Amẹ́ríkà láti wá ojútùú sí ààbò tó mẹ́hẹ, àbọ̀ wọn rèé
Awọn gomina lapa ariwa ni awọn ti ri awọn aṣiri kan to ju ti tẹlẹ lọ, eyi tawọn le fi koju iṣoro aabo to mẹhẹ naa.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Móríwú
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Mọ̀ nípa ẹgbẹ́ kan tó wà fún àwọn obìnrin tí kò fẹ́ l'ọ́mọ láyé
Ileeṣẹ BBC ba awọn obinrin to jẹ ọmọ ẹgbẹ Bristol Childfree Women sọrọ, wọn si salaye idi ti wọn ri ti wọn fi pinnu igbesẹ yii.
Kí ló dé tí wàhálà bẹ̀rẹ̀ bí Togo ṣe fẹ́ kúrò nílànà òṣèlú ààrẹ sí ìṣèjọba ẹlẹ́kùnjẹkùn?
Atunṣe iwe ofin ni ọdun 2019 fi aye gba Aarẹ Gnassingbe lati jade dupo, eyi to fun ni anfani lati wa nipo títi wọ ọdun 2030.
Kí ni El Niño àti La Niña, kí ní àjọṣepọ̀ wọn pẹ̀lú ojú ọjọ́?
El Niño ati La Niña, mejeeji yii jẹ ohun pataki si ayipada oju-ọjọ lagbaye.
Ẹ má kó oúnjẹ 5000 tí mo pín lọ sílé yín, àwọn mẹ̀kúnnù tó nílò rẹ̀ ni kí ẹ pín fún - Sanwo-Olu kìlọ̀
Ijọba Eko ni awọn eeyan ijọba ibilẹ ogun ati tawọn onidagbasoke (LCDA) mẹtadinlogoji to wa l’Ekoo ni yoo janfaani ounjẹ naa.
Àlàyé rèé lórí ìdí tí Amẹ́ríkà ṣe fẹ́ fòfin de TikTok
Aarẹ Amẹrika tẹlẹ ri, Donald Trump naa gbiyanju lọdun 2020 lati fofin de TikTok lasiko ijọba rẹ.
Mo ti bá olóòtú fíìmù lòpọ̀ rí, kí n lè kópa nínú sinimá rẹ̀ – Seun Sean Jimoh
Seun Sean Jimoh bo tilẹ jẹ pe iṣẹlẹ naa ti kuregbe-kuregbe, o ni o ṣi maa n ba oun ninu jẹ titi di oni yii.
Wàhálà míí tún bá Emefiele, EFCC ní odidi N18.9bn ló fi tẹ owó péréte N684.5m, òun yóò ba ṣe ẹjọ́ míì
Ọgbọnjọ oṣu Kẹrin ọdun yii ni Emefiele yoo foju ba ile ẹjọ niwaju adajọ Maryann Anenih ile ẹjọ giga ijọba apapọ niluu Abuja.